03 May 2009 |
|
Ninu iwe Iyovu tọn pe ni Jobu, Ẹyin ni Ẹ fi ọla, iyin, ogo ati ẹwa bo ara Yin bi aṣọ (In the book of Iyov called Job, You have clothed Yourself with majesty, excellence, glory and beauty). Ninu iwe Tehillim tọn pe ni Orin Dafidi, Ẹyin ni Oluwa to tobi ti o si lagbara, oye Yin ko ni wọn (In the book of Tehillim called Psalms, You are the great Lord, of great power, Your understanding is infinite). Ninu iwe Miṣlei tọn pe ni Iwe Owe, Ẹyin ni asa fun awon ti o fi igbekele won sinu Yin. (In the book of Mishlei called Proverbs, You are a shield to those who put their trust in You). Ninu iwe Koheleti tọn pe ni Iwe Oniwasu, Ẹyin ni Ọlọrun tin mu ohun gbogbo wa si idajọ (In the book of Kohelet called Ecclesiastes, The God that brings every work into judgment). Ninu iwe ṢirHaṣirim tọn pe ni Orin Solomọni, Ẹyin ni (In the book of Shir HaShirim called Songs of Solomon, You are the chiefest among ten thousand). Ninu iwe Yeṣayahu tọn pe ni Aisaya Ẹyin ni Iyanu, Oludamoran, Ọlọrun Alagbara, Ọmọ Alade alafia, Baba ayeraye (In the book of Yesha’yahu called Isaiah, Wonderful, Counselor, Mighty God, Prince of peace, Everlasting Father). Ninu iwe Yameyahu tọn pe ni Jeremaya, Ẹyin l’orisun omi iye (In the book of Yirmeyahu called Jeremiah, You are the Fountain of living waters). Ninu iwe Eikha tọn pe ni Ẹkun Jeremaya, Ẹyin ni Oluwa, Ipin wa, Eni ti awa nṣe ireti ninu (In the book of Eikhah called Lamentations, You are the Lord, our Portion, the One we hope in). Ninu iwe Yekesikel tọn pe ni Isikiẹli, Ẹyin ni Olufunni lọkan titun ati ẹmi titun (In the book of Yechezk’el called Ezekiel, You are the Giver of a new heart and a new spirit). Ninu iwe Daniyel tọn pe ni Ẹyin ni Ọlọrun to wa laaye (In the book of Dani’el called Daniel, You are the Living God). Ninu iwe Hoṣea tọn pe ni Hosia, Ẹyin ni Oluwa, Ọlọrun awọn ọmọ ogun (In the book of Hoshea called Hosea, You are the Lord God of hosts). Ninu iwe Yohel tọn pe ni Joẹli, Ẹyin ni Ireti ati Agbara awọn enia Yin (In the book of Yo’el called Joel, You are the Hope and Strength of Your people). Ninu iwe Hamos tọn pe ni Amọsi, Ẹyin ni Oluwa Ọlọrun tiun bura nipa ododo Rẹ (In the book of ‘Amos called Amos, You are the Lord God that swears by His holiness). Ninu iwe Hovadiyah* tọn pe ni Ọbadaya Ẹyin ni Olugbala awọn enia Yin (In the book of ‘Ovadyah called Obadiah, You are the Deliverer of Your people). Ninu iwe Yona tọn pe ni Jona, Ẹyin ni Oluwa to ni igbala (In the book of Yonah called Jonah, You are the Lord with salvation). Ninu iwe Mikha tọn pe ni Mika, Ẹyin ni Ọlọrun to ni idunnu ninu anu (In the book of Mikhah called Micah, You are the God that delights in mercy). Ninu iwe Nakum tọn pe ni Nahumu, Ẹyin ni Oluwa to dara, Abo ni ọjọ ipọnju, Ẹ si mọ awọn to jẹ ti Yin (In the book of Nachum called Nahum, You are Good, and a stronghold in the day of trouble, and You know those who are Yours). Ninu iwe Havakuk tọn pe ni Habakuku, Ẹyin ni Oloju mimọ ju lati wo ibi (In the book of Havakuk called Habakkuk, You are the One with purer eyes than to behold evil). Ninu iwe Sifanya tọn pe ni Sefanaya, Ẹyin ni Ọlọrun ododo ti kii ṣe ẹṣẹ, lararọ, Ẹ mu idajọ Yin si imọle (In the book of Tz’fanyah called Zephaniah, You are the just Lord that does not do iniquity, every morning, You bring Your judgment to light).
Ninu iwe Hagayi tọn pe ni Hagai, Ẹyin ni Oluwa to wa pẹlu wa (In the book of Hagai called Haggai, You are the Lord with us).
Ninu iwe Zekarya tọn pe ni Sakaraya, Ẹyin ni Ọba na, Ọlọrun awọn ọmọ ogun (In the book of Z’kharyah called Zechariah, You are the King, the Lord of hosts).
Ninu iwe Malaki tọn pe Malaki ni Ẹyin ni Oluwa, Ẹ ko si yipada (In the book of Mal’akhi called Malachi, You are the Lord, and You do not change).
Ninu iwe Matiyahu tọn pe ni Ẹyin ni (In the book of Mattityahu called Matthew, Our Savior, the One Who delivered us from our sins).
Ninu iwe Marku tọn pe ni Mark, Ẹyin ni Olubamptisi pẹlu Ẹmi Mimọ (In the book of Mark, You are the Baptizer with the Holy Spirit).
Ninu iwe Luku tọn pe ni Luke, Ẹyin ni Igbala Ọlọrun (In the book of Luke, You are the Salvation of God).
Ninu iwe Yokanan tọn pe ni Johanu, Ẹyin ni Ọrọ Ọlọrun (In the book of Yochanan called John, You are the Word of God).
Ninu iwe Iṣẹ awọn ẹmisari Yeṣua tọn pe ni Iwe iṣe awon aposteli, Ẹyin ni Olukunni l’Ẹmi Mimọ (In the book of Acts of the Emissaries of Yeshua called Acts of the apostles, You are the Infiller of the Holy Spirit).
Ninu iwe Ara awọn Romu Ẹyin ni Ọmọ Ọlọrun (In the book of Romans, You are the Son of God).
Ninu iwe Awọn ara Korinti kini, Ẹyin ni Oluwa Ologo,(In the book of 1 Corinthians, You are the Lord of glory).
Ninu iwe Awọn ara Korinti keji, Ẹyin ni Ẹ kun fun ore–ọfẹ tẸ di talaka ki awa ba le di ọlọrọ (In the book of 2 Corinthians, You are the gracious One that became poor that we might be rich).
Ninu iwe Awọn ara Galaṣia, Ẹyin ni Ẹni to fẹran wa to fi aye Rẹ fun wa, nipa igbagbọ Yin la fi wa (In the book of Galatians, The One who loved us and gave Himself for us, by whose faith we live).
Ninu iwe tọn pe ni Ẹyin ni Alafia wa (In the book of Ephesians, You are our Peace).
Ninu iwe Awọn ara Filipi, Ẹyin ni Ẹni orukọ to ju gbogbo orukọ lọ (In the book of Philippians, You are the One with the Name above every name).
Ninu iwe Awọn ara Kolosse, Ẹyin ni Aworan Ọlọrun ti a ko ri, Akọbi gbogbo ẹda (In the book of Colossians, You are the Image of the invisible God, the First born of every creature).
Ninu iwe Awọn ara Tesalonika kini, Ẹyin ni Ọmọ Ọlọrun ni ọrun to gbawa lọwọ ibinu tiun bọ, (In the book of I Thessalonians, You are the Son of God in heaven Who delivered us from the wrath to come).
Ninu iwe Awọn ara Tesalonika keji, Ẹyin ni Oluwa olododo tii fie se wa mule tiun si pawa mo kuro ninu ibi gbogbo (In the book of 2 Thessalonians, You are the faithful Lord Who establishes us and keeps us from all evil).
Ninu iwe Timoti kinni, Ẹyin ni Ọlọrun Olugbala wa ati Oluwa, Ireti wa (In the book of 1 Timothy, You are God our Savior and Lord, and our hope).
Ninu iwe iwe Timoti keji, Ẹyin ni Apakurẹ, Afuni niye ati Afi aidibajẹ han (In the book of 2 Timothy, You are the abolisher of death, giver of life and Revealer of immortality).
Ninu iwe Titu, Ẹyin ni Ore-ọfẹ Ọlọrun (In the book of Titus, You are the Grace of God).
Ninu iwe Filemoni, Ẹyin ni Oninkan ati Afuni loun rere gbogbo (In the book of Philemon, You are the Owner and giver of every good thing).
Ninu iwe Heberu, Ẹyin ni Oluwa ologo (In the book of Hebrews, You are the Lord of glory).
Ninu iwe Yakọvu tọn pe ni Jakobu, Ẹyin ni Oluwa awọn ọmọ ogun (In the book of Ya’akov called James, You are the Lord of Sabaoth).
Ninu iwe Kefa kini tọn pe ni Peteru kini Ẹyin ni Olutọju awọn olododo di igba ti igbala yio yọ (In the book of 1 Kefa called 1 Peter, You are the Keeper of the saints till the revealed salvation).
Ninu iwe Kefa keji tọn pe ni Peteru keji, Ẹyin ni Ẹni ti o ti gba iyi ati ogo lat’ọdọ Ọlọrun Baba (In the book of 2 Peter, You are the One who received honor and glory from God the Father). Ninu iwe Yochanan kini tọn pe ni Johanu kini Ẹyin ni Ifẹ, Ifẹ Ọlọrun (In the book of 1 John, You are Love, the Love of God).
Ninu iwe Yochanan keji tọn pe ni Johanu keji Ẹyin ni Ọmọ Baba ni otitọ ati ifẹ (In the book of 2 John, You are the Son of the Father in truth and love).
Ninu iwe Yochanan kẹta tọn pe ni Johanu kẹta Ẹyin ni Otitọ Ọlọrun (In the book of 3 John, The truth of God).
Ninu iwe Yuhuda tọn pe ni Juda, Ẹyin ni Ọlọrun nikanṣo to gbọn, Olugbala wa, Ẹni ti gba gbogbo ogo, ọla nla, ijọba ati agbara nisisiyi ati lailai (In the book of Y’hudah called Jude, You are the only wise God, our Savior Who receives all glory, majesty, dominion and power, now and forever).
Ninu iwe Revelationu tọn pe ni Iwe Ifihan, Ẹyin ni Ẹleri olododo, Akọbi lati oku, Ọmọ Ọba awọn ọba aye, Awe ẹṣẹ ẹlẹṣẹ mọ pelu ẹjẹ Yin (In the book of Revelations, You are the faithful witness, the first begotten of the dead, the prince of the kings of the earth, the Cleanser of sinners from their sins by your blood). Iyinayọ sang the chorus again and Madam Eriokan’s pastor came over. He had everyone stand up and pray for her. When all was finished I gave the microphone to Iyinayọ to introduce themselves and I then said: Tọ ba bere pe talo k’ewi (If they ask who recited the poem). Tẹ ba fẹ mọ eni ti Ẹmi mimọ lo lati jiṣẹ Rẹ (If you want to know the person whom the Holy Spirit used to deliver His message). Kẹ lemi ni, Derbrah Adeṣọla, ọmọ Yud-He-Vav-He* (Say that it’s me, Derbrah Adeṣọla, child of Yud-Heh-Vav-Heh). Derbrah ti awọn Ju npe ni Divora (Derbrah, that the Jews call D’vorah) Adeṣọla tiun polongo ore-ọfẹ** Jesu Kristi, (Crown made wealth that markets the grace of Jesus Christ). AdeYesuaMesaya ṣọlaninu ayemi (The crown of Yeshua Messiah has created wealth in my life). Ọmọ ti ẹjẹ Jesu ra pada (The child that the blood of Jesus redeemed). Mo ṣeba fun Baba, Ọmo ati Ẹmi Mimọ (I give tribute to the Father, Son and Holy Spirit). Making the “oṣuba” (honor) sign, I concluded, Ẹṣe Ẹlohim tẹ gba’ba wa, aa yin Yin, aa gbe Yin ga (Thank You Elohim for receiving our tribute We praise You, we lift You up). After that the audience gave a resounding ovation and we all returned to our seats.
Feyi announced an intermission before the all night dance session began so I beckoned to Igbala that it was home time. She left to use the bathroom while I fellowshipped with friends and many who came to affirm my presentation. Jibafẹ took me to madam Eriọkan who showered me with love. She also introduced Igbala to her. As we left to my car Jibafẹ muttered that she was feeling whoozy again. Igbala shook her head and said, “I think you’re pregnant, I saw you with a baby.” Jibafẹ stopped in her tracks and gasped, “Of course, that explains it.” She said her goodbyes and ran to Jagun. In the car I mentioned to Igbala that I bet Jibafe would stop to buy a pregnancy test on her way home. After dropping Igbala off I glanced at my watch, it was almost midnight, it’s been a long day but I had enjoyed it. * There is no letter “v” in Yoruba alphabets however, in order to properly pronounce and translate Hebrew words directly, especially the Tetragrammaton, the letter “v” is used, Yoruba language too has “evolved” like other languages. ** There is no Yoruba word for grace hence the use of ore-ọfẹ which really means free gift. Derbrah writes courtesy of Agape for All Ministries. Author retains copyright. Jadesọla’s restaurant is a drama ministry of the Yoruba Christian Women (YCW), an international faith-based non-governmental, not-for-profit organization. Similarity of names and stories are coincidental. Feel free to copy for non-commercial use. Commercial use requires permission. For more information on YCW write Jesutoyin Ajikẹ-King (toyinking@yahoo.com).
|
|||||||||







Your Comments
Please make The Square an enjoyable experience for everyone by refraining from gratuitous ad-hominem contributions, defamatory comments and off-topic posting. Such posts will be removed.